Universal Declaration of Human Rights - Yoruba (Yorùbá)
Content Category
Yoruba (Yorùbá)
ÌKÉDE KÁRÍAYÉ FÚN È̟TÓ̟ O̟MO̟NÌYÀN Ò̟RÒ̟ ÀKÓ̟SO̟ Bí ó ti jé̟ pé s̟ís̟e àkíyèsí iyì tó jé̟ àbímó̟ fún è̟dá àti ìdó̟gba è̟tó̟ t̟̟̟̟í kò s̟eé mú kúrò tí è̟dá kò̟ò̟kan ní, ni òkúta ìpìlè̟ fún òmìnira...